The Popes
Grateful cover

Lyrics & meaning

Grateful

Aṣa (singer-songwriter blending soul, pop, folk,)

◎ Bed of Stone✎ 0 annotations0 comments
Era ilẹ', era ilẹ', wọn yìn Bàbá l'òkè 'Yanrìn, òkun, 'yanrìn, òkun, wọn yìn Bàbá l'òkè Ẹranko ilé, ẹranko igbó, wọn yín Bàbá l'òkè Àwọn aláìní, àwọn tán tí ní, wọn yìn Bàbá l'òkè Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yán Kò tó mọ pé Bàbá ń bẹ l'òkè Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yán Kò tó mọ pé loótọ' ò ńbẹ l'òkè You don't have to wait 'til you feel the pain You can start right now It's not too late It's not too late to be grateful! Ah, ah, uhm Ah, ah, ah, ah-ah, ah Hmm-mmm Era ilẹ', era ilẹ', wọn yìn Bàbá l'òkè 'Yanrìn òkun, 'yanrìn òkun, wọn yìn Bàbá l'òkè Pé mo wà láyé, mo wà láàyè Gbogbo òun tí mò ní, má fí yìn ò lógo Believe this world a better place Ah-ah-ah, eh-eh Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yàn Kò tó mọ pé Bàbá ńbẹ l'òkè (okay) Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yàn Kò tó mọ pé loótọ' ò ńbẹ l'òkè You don't have to wait 'til you feel the pain You can start right now (okay) It's not too late (it's not too late) It's not too late to be grateful (yes) Ahh O rí bí mo ṣe ńf'ẹgbẹ yìn Bàbá Ta, du-ba, du-ba (hey) Ta, du-ba, du-bu (hey) Ba, du-ba, du-ba (hey) Da, du-da, du-bu (hey) It's not too late Uhh-uh-uh, eh (hey) Ta, du-ba, du-bu (yeah-yeah, oh, that's right)

The conversation00

Got a take on this song? Join the conversation.

Sign in to comment

No comments yet — be the first to say something.