THE POPES
Formation cover

Formation

Adekunle Gold

All my ladies formation All my ladies- For-For-Forma- All my ladies formation If you're sexy, go low-low Fine bọbọ, wetin sup? If you want it, ṣè ò l'òwò? (L'òwò) Fuck with me, baby, don't let me go Stop it, don't call me bro Èwò l'èwò? Sisi Eko Baby hello She say, "Oh, my Lord Talk is cheap, show me working" Ha, ṣ'òun tẹ button? K'òlè rẹ bod Ẹ pè money changer t'òn ṣẹ'wò Electro Fuji l'ọfẹ jò Talazo wese, ẹ má gbọ Bureau de change, Kwankwanso Ẹ pè money changer t'òn ṣẹ'wò Kosoko music l'ọfẹ jò Talazo wese, ẹ má gbọ Bureau de change, Kwankwanso (oh-oh) Yè, filẹ si'bẹ (ah-ah-ahn) Jẹ ò wá bẹ, ẹ jẹ k'òlọ bẹ Wọn fẹ mọ bi mò ṣè jẹ Ọmọ iyámi, no dey vex Ẹ sọh fun kò stop ṣè'bẹ Ọmọl'ọmọ, wọn ni ibò l'oti r'òwò nà? Iṣẹ kèkèrè, òwò nlá-nlá Wọn lè, wọn lè, wọn 'lè bá (Dey with me), wọn 'lè bá Million-million dollar l'òn na dollar No be small-small dollar No be young-young dollar t'òn nà dollar Áwọn young dullards Three comma-comma l'ògbè comma, òwò Otedola Stay close to me, my baby U.I gate to Mokola Òlòlufẹ mi, baby (baby) Iwọ ṣámá rè'di (rè'di) Whenever you ready (ready) Ki iwọ ṣá ti pè mi (pè mi) Anything t'òbá fẹ B'òjẹ òwurọ or l'álẹ T'òbá jẹ hardcover l'òfẹ Má ṣánà siẹ l'ábẹ, l'ábẹ, l'ábẹ Ẹ pè money changer t'òn ṣẹ'wò Electro Fuji l'ọfẹ jò Talazo wese, ẹ má gbọ Bureau de change, Kwankwanso Ẹ pè money changer t'òn ṣẹ'wò Kosoko music l'ọfẹ jò Talazo wese, ẹ má gbọ (ayy) Bureau de- (Talazo wi, Kwankwanso oh-oh) Yè, filẹ si'bẹ (ah-ah-ahn) Jẹ ò wá bẹ, ẹ jẹ k'òlọ bẹ Wọn fẹ mọ bi mò ṣè jẹ Ọmọ iyámi, no dey vex Ẹ sọh fun kò stop ṣè'bẹ Ọmọl'ọmọ, wọn ni ibò l'oti r'òwò nà? Iṣẹ kèkèrè, òwò nlá-nlá

Comments (0)

Sign in to join the discussion.

No comments yet. Start the conversation.